29 Gbogbo ẹni tó bá sì ti fi àwọn ilé tàbí àwọn arákùnrin, àwọn arábìnrin, bàbá, ìyá, àwọn ọmọ tàbí àwọn ilẹ̀ sílẹ̀ nítorí orúkọ mi máa gba ìlọ́po ọgọ́rùn-ún (100), ó sì máa jogún ìyè àìnípẹ̀kun.+
26 “Tí ẹnikẹ́ni bá wá sọ́dọ̀ mi, tí kò sì kórìíra* bàbá, ìyá, ìyàwó, àwọn ọmọ, àwọn arákùnrin àti àwọn arábìnrin rẹ̀, àní ẹ̀mí*+ òun fúnra rẹ̀ pàápàá, kò lè di ọmọ ẹ̀yìn mi.+