-
Ẹ́kísódù 23:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Tí o bá rí i tí akọ màlúù tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ọ̀tá rẹ ń ṣìnà, kí o dá a pa dà fún un.+
-
-
Diutarónómì 22:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Tí o bá rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tàbí akọ màlúù arákùnrin rẹ tó ṣubú lójú ọ̀nà, má mọ̀ọ́mọ̀ mójú kúrò. Rí i dájú pé o bá a gbé ẹran náà dìde.+
-