ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 3:28, 29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín pé, ohun gbogbo la máa dárí rẹ̀ ji àwọn ọmọ èèyàn, ẹ̀ṣẹ̀ èyíkéyìí tí wọ́n bá dá àti ọ̀rọ̀ òdì èyíkéyìí tí wọ́n bá sọ. 29 Àmọ́, ẹnikẹ́ni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́, kò lè ní ìdáríjì kankan títí láé,+ àmọ́ ó máa jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ àìnípẹ̀kun.”+

  • Ìṣe 7:51
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+

  • Hébérù 6:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Torí ní ti àwọn tí a ti là lóye rí,+ tí wọ́n ti tọ́ ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ti ọ̀run wò, tí wọ́n sì ti ní ìpín nínú ẹ̀mí mímọ́,

  • Hébérù 6:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 àmọ́ tí wọ́n yẹsẹ̀,+ kò ṣeé ṣe láti tún mú wọn sọ jí kí wọ́n lè ronú pìwà dà, torí ṣe ni wọ́n tún kan Ọmọ Ọlọ́run mọ́gi* fún ara wọn, wọ́n sì dójú tì í ní gbangba.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́