Mátíù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tó rí i tí ọ̀pọ̀ lára àwọn Farisí àti Sadusí+ ń wá síbi ìrìbọmi náà, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin ọmọ paramọ́lẹ̀,+ ta ló kìlọ̀ fún yín pé kí ẹ sá fún ìbínú tó ń bọ̀?+ Mátíù 23:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 “Ẹ̀yin ejò, ọmọ paramọ́lẹ̀,+ báwo lẹ ṣe máa bọ́ nínú ìdájọ́ Gẹ̀hẹ́nà?*+
7 Nígbà tó rí i tí ọ̀pọ̀ lára àwọn Farisí àti Sadusí+ ń wá síbi ìrìbọmi náà, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin ọmọ paramọ́lẹ̀,+ ta ló kìlọ̀ fún yín pé kí ẹ sá fún ìbínú tó ń bọ̀?+