Máàkù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó tún bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ni létí òkun, èrò rẹpẹtẹ sì kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ̀. Torí náà, ó wọ ọkọ̀ ojú omi, ó sì jókòó sínú rẹ̀, ó sún kúrò ní etíkun, àmọ́ gbogbo àwọn èrò náà wà ní èbúté, létí òkun.+
4 Ó tún bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ni létí òkun, èrò rẹpẹtẹ sì kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ̀. Torí náà, ó wọ ọkọ̀ ojú omi, ó sì jókòó sínú rẹ̀, ó sún kúrò ní etíkun, àmọ́ gbogbo àwọn èrò náà wà ní èbúté, létí òkun.+