ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 4:30-32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Ó ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Kí la lè fi Ìjọba Ọlọ́run wé, àbí àpèjúwe wo la lè fi ṣàlàyé rẹ̀? 31 Ó dà bíi hóró músítádì, tó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n gbìn ín sínú ilẹ̀, òun ló kéré jù lọ nínú gbogbo irúgbìn tó wà láyé.+ 32 Àmọ́ lẹ́yìn tí wọ́n gbìn ín, ó dàgbà, ó sì tóbi ju gbogbo ọ̀gbìn oko yòókù lọ, ó yọ àwọn ẹ̀ka ńláńlá, débi pé àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run wá ń gbé lábẹ́ òjìji rẹ̀.”

  • Lúùkù 13:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ó wá sọ pé: “Kí ni Ìjọba Ọlọ́run jọ, kí sì ni mo lè fi wé? 19 Ó dà bíi hóró músítádì tí ọkùnrin kan mú, tó sì gbìn sínú ọgbà rẹ̀, tó wá dàgbà, tó sì di igi, tí àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì fi àwọn ẹ̀ka rẹ̀ ṣe ibùgbé.”+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́