Mátíù 13:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ẹ jẹ́ kí méjèèjì jọ dàgbà títí dìgbà ìkórè, tó bá wá dìgbà ìkórè, màá sọ fún àwọn tó ń kórè pé: Ẹ kọ́kọ́ kó àwọn èpò jọ, kí ẹ sì dì wọ́n ní ìdìpọ̀-ìdìpọ̀ láti sun wọ́n; kí ẹ wá kó àlìkámà jọ sínú ilé ìkẹ́rùsí mi.’”+
30 Ẹ jẹ́ kí méjèèjì jọ dàgbà títí dìgbà ìkórè, tó bá wá dìgbà ìkórè, màá sọ fún àwọn tó ń kórè pé: Ẹ kọ́kọ́ kó àwọn èpò jọ, kí ẹ sì dì wọ́n ní ìdìpọ̀-ìdìpọ̀ láti sun wọ́n; kí ẹ wá kó àlìkámà jọ sínú ilé ìkẹ́rùsí mi.’”+