ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 10:35-40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 35 Jémíìsì àti Jòhánù, àwọn ọmọ Sébédè,+ wá bá a, wọ́n sì sọ fún un pé: “Olùkọ́, a fẹ́ kí o ṣe ohunkóhun tí a bá béèrè lọ́wọ́ rẹ fún wa.”+ 36 Ó sọ fún wọn pé: “Kí lẹ fẹ́ kí n ṣe fún yín?” 37 Wọ́n fèsì pé: “Gbà wá láyè ká jókòó, ọ̀kan ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti ọ̀kan ní òsì rẹ, nínú ògo rẹ.”+ 38 Àmọ́ Jésù sọ fún wọn pé: “Ẹ ò mọ ohun tí ẹ̀ ń béèrè. Ṣé ẹ lè mu ife tí mò ń mu àbí a lè batisí yín bí a ṣe ń batisí mi?”+ 39 Wọ́n sọ fún un pé: “A lè mu ún.” Jésù wá sọ fún wọn pé: “Ẹ máa mu ife tí mò ń mu, a sì máa batisí yín bí a ṣe ń batisí mi.+ 40 Àmọ́ èmi kọ́ ló máa sọ ẹni tó máa jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi tàbí sí òsì mi, ṣùgbọ́n ó máa wà fún àwọn tí a ti ṣètò rẹ̀ fún.”

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́