ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 21:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Torí Jòhánù wá sọ́dọ̀ yín ní ọ̀nà òdodo, àmọ́ ẹ ò gbà á gbọ́. Ṣùgbọ́n àwọn agbowó orí àti àwọn aṣẹ́wó gbà á gbọ́,+ kódà nígbà tí ẹ rí èyí, ẹ ò pèrò dà lẹ́yìn náà kí ẹ lè gbà á gbọ́.

  • Máàkù 11:30, 31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Ṣé láti ọ̀run ni ìrìbọmi tí Jòhánù+ ṣe fún àwọn èèyàn ti wá àbí látọ̀dọ̀ èèyàn?* Ẹ dá mi lóhùn.”+ 31 Wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí í rò ó láàárín ara wọn, wọ́n ní: “Tí a bá sọ pé, ‘Láti ọ̀run,’ ó máa sọ pé, ‘Kí ló wá dé tí ẹ ò gbà á gbọ́?’

  • Lúùkù 7:29, 30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 (Nígbà tí gbogbo èèyàn àti àwọn agbowó orí gbọ́ èyí, wọ́n kéde pé olódodo ni Ọlọ́run, torí Jòhánù ti ṣe ìrìbọmi fún wọn.+ 30 Àmọ́ àwọn Farisí àti àwọn tó mọ Òfin dunjú kò ka ìmọ̀ràn* tí Ọlọ́run fún wọn sí,+ torí pé kò tíì ṣe ìrìbọmi fún wọn.)

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́