Mátíù 21:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn èrò náà ń sọ ṣáá pé: “Jésù nìyí, wòlíì+ tó wá láti Násárẹ́tì ti Gálílì!” Jòhánù 7:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Àwọn kan láàárín èrò tí wọ́n gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ yìí bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Wòlíì náà nìyí lóòótọ́.”+