ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 1:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ó sì ń wàásù pé: “Ẹnì kan tó lágbára jù mí lọ ń bọ̀ lẹ́yìn mi, ẹni tí mi ò tó bẹ̀rẹ̀ láti tú okùn bàtà rẹ̀.+ 8 Mò ń fi omi batisí yín, àmọ́ ó máa fi ẹ̀mí mímọ́ batisí yín.”+

  • Jòhánù 1:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Èmi gan-an ò mọ̀ ọ́n, àmọ́ Ẹni tó rán mi láti fi omi batisí sọ fún mi pé: ‘Ẹnikẹ́ni tí o bá rí tí ẹ̀mí ń sọ̀ kalẹ̀, tó sì bà lé,+ òun ni ẹni tó ń fi ẹ̀mí mímọ́ batisí.’+

  • Ìṣe 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ní ọjọ́ Àjọyọ̀ Pẹ́ńtíkọ́sì,+ gbogbo wọn wà níbì kan náà, bí àjọyọ̀ náà ṣe ń lọ lọ́wọ́.

  • Ìṣe 2:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 gbogbo wọn wá kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ oríṣiríṣi èdè,* bí ẹ̀mí ṣe mú kí wọ́n máa sọ̀rọ̀.+

  • 1 Kọ́ríńtì 12:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nítorí ipasẹ̀ ẹ̀mí kan ni a batisí gbogbo wa sínú ara kan, ì báà jẹ́ Júù tàbí Gíríìkì, ẹrú tàbí òmìnira, a sì mú kí gbogbo wa gba* ẹ̀mí kan.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́