-
Mátíù 13:52Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
52 Ó wá sọ fún wọn pé: “Tó bá rí bẹ́ẹ̀, gbogbo ẹni tó ń kọ́ni ní gbangba, tí a kọ́ nípa Ìjọba ọ̀run, dà bí ọkùnrin kan tó jẹ́ baálé ilé, tó kó àwọn ohun tuntun àti ohun àtijọ́ jáde látinú ibi tó ń kó ìṣúra sí.”
-