Mátíù 16:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Torí Ọmọ èèyàn máa wá nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀, ó máa wá san èrè fún kálukú gẹ́gẹ́ bí ìwà rẹ̀.+
27 Torí Ọmọ èèyàn máa wá nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀, ó máa wá san èrè fún kálukú gẹ́gẹ́ bí ìwà rẹ̀.+