Diutarónómì 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ dán Jèhófà Ọlọ́run yín wò,+ bí ẹ ṣe dán an wò ní Másà.+ Lúùkù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jésù dá a lóhùn pé: “A sọ ọ́ pé, ‘O ò gbọ́dọ̀ dán Jèhófà* Ọlọ́run rẹ wò.’”+ 1 Kọ́ríńtì 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Bẹ́ẹ̀ ni kí a má ṣe dán Jèhófà* wò,+ bí àwọn kan nínú wọn ṣe dán an wò, tí ejò sì ṣán wọn pa.+