-
Máàkù 14:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ó dájú pé mi ò ní mu nínú ohun tí wọ́n fi àjàrà ṣe mọ́, títí di ọjọ́ yẹn tí màá mu ún ní tuntun nínú Ìjọba Ọlọ́run.”
-
-
Lúùkù 22:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 torí mò ń sọ fún yín, láti ìsinsìnyí lọ, mi ò tún ní mu àwọn ohun tí wọ́n fi àjàrà ṣe mọ́ títí Ìjọba Ọlọ́run fi máa dé.”
-