Sáàmù 110:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+ Lúùkù 22:69 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 69 Àmọ́ láti ìsinsìnyí lọ, Ọmọ èèyàn+ máa jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún agbára Ọlọ́run.”+
110 Jèhófà sọ fún Olúwa mi pé: “Jókòó sí ọwọ́ ọ̀tún mi+Títí màá fi fi àwọn ọ̀tá rẹ ṣe àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”+