-
Máàkù 15:11-14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àmọ́ àwọn olórí àlùfáà ru àwọn èrò náà sókè pé kí wọ́n ní kó tú Bárábà sílẹ̀ fún àwọn dípò rẹ̀.+ 12 Pílátù tún fún wọn lésì pé: “Kí wá ni kí n ṣe sí ẹni tí ẹ̀ ń pè ní Ọba Àwọn Júù?”+ 13 Wọ́n ké jáde lẹ́ẹ̀kan sí i pé: “Kàn án mọ́gi!”*+ 14 Àmọ́ Pílátù sọ fún wọn pé: “Kí ló dé? Nǹkan burúkú wo ló ṣe?” Síbẹ̀, wọ́n túbọ̀ kígbe pé: “Kàn án mọ́gi!”+
-