ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 9:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àmọ́, ìṣúdùdù náà kò ní rí bí ìgbà tí ìdààmú bá ilẹ̀ náà, bí ìgbà àtijọ́ tí wọ́n hùwà àbùkù sí ilẹ̀ Sébúlúnì àti ilẹ̀ Náfútálì.+ Àmọ́ tó bá yá, Ó máa mú kí a bọlá fún un, ní ọ̀nà ibi òkun, ní agbègbè Jọ́dánì, Gálílì àwọn orílẹ̀-èdè.

       2 Àwọn èèyàn tó ń rìn nínú òkùnkùn

      Ti rí ìmọ́lẹ̀ tó mọ́lẹ̀ yòò.

      Ní ti àwọn tó ń gbé ilẹ̀ tó ṣókùnkùn biribiri,

      Ìmọ́lẹ̀ ti tàn sórí wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́