ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 5:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Tí àwọn èèyàn bá tan fìtílà, wọn kì í gbé e sábẹ́ apẹ̀rẹ̀,* orí ọ̀pá fìtílà ni wọ́n ń gbé e sí, á sì tàn sára gbogbo àwọn tó wà nínú ilé.+

  • Lúùkù 8:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “Kò sí ẹni tó máa tan fìtílà, tó máa wá fi nǹkan bò ó tàbí kó gbé e sábẹ́ ibùsùn, àmọ́ orí ọ̀pá fìtílà ló máa gbé e sí, kí àwọn tó bá wọlé lè rí ìmọ́lẹ̀.+ 17 Torí kò sí nǹkan tí a fi pa mọ́ tí kò ní hàn kedere, kò sí ohun tí a rọra tọ́jú tí a ò ṣì ní mọ̀, tí kò sì ní hàn sí gbangba.+

  • Lúùkù 11:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Tí ẹnì kan bá tan fìtílà, kò ní gbé e síbi tó fara pa mọ́ tàbí sábẹ́ apẹ̀rẹ̀,* àmọ́ orí ọ̀pá fìtílà ló máa gbé e sí,+ kí àwọn tó bá wọlé lè rí ìmọ́lẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́