-
Mátíù 13:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ní, a máa fi kún ohun tó ní, a sì máa mú kó ní púpọ̀; àmọ́ ẹnikẹ́ni tí kò bá ní, a máa gba ohun tó ní pàápàá kúrò lọ́wọ́ rẹ̀.+
-
-
Lúùkù 19:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 ‘Mò ń sọ fún yín, gbogbo ẹni tó bá ní, a máa fi kún èyí tó ní, àmọ́ ẹni tí kò bá ní, a máa gba èyí tó ní pàápàá lọ́wọ́ rẹ̀.+
-