38 Àmọ́ ọkùnrin tí àwọn ẹ̀mí èṣù jáde lára rẹ̀ ń bẹ̀ ẹ́ ṣáá pé òun fẹ́ bá a lọ, ṣùgbọ́n ó ní kí ọkùnrin náà máa lọ, ó ní:+ 39 “Pa dà sílé, kí o sì máa ròyìn ohun tí Ọlọ́run ṣe fún ọ.” Torí náà, ó lọ, ó ń kéde ohun tí Jésù ṣe fún un káàkiri gbogbo ìlú náà.