Ìṣe 2:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Pétérù sọ fún wọn pé: “Ẹ ronú pìwà dà,+ kí a sì batisí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín+ ní orúkọ Jésù Kristi, kí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín lè ní ìdáríjì,+ ẹ ó sì gba ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ẹ̀mí mímọ́. Ìṣe 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Nítorí náà, ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì yí pa dà,+ kí Ọlọ́run lè pa àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín rẹ́,+ kí àwọn àsìkò ìtura lè wá látọ̀dọ̀ Jèhófà fúnra rẹ̀,*
38 Pétérù sọ fún wọn pé: “Ẹ ronú pìwà dà,+ kí a sì batisí ẹnì kọ̀ọ̀kan yín+ ní orúkọ Jésù Kristi, kí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín lè ní ìdáríjì,+ ẹ ó sì gba ẹ̀bùn ọ̀fẹ́ ẹ̀mí mímọ́.
19 “Nítorí náà, ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì yí pa dà,+ kí Ọlọ́run lè pa àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín rẹ́,+ kí àwọn àsìkò ìtura lè wá látọ̀dọ̀ Jèhófà fúnra rẹ̀,*