-
Ìṣe 27:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Lẹ́yìn tó sọ ọ̀rọ̀ yìí, ó mú búrẹ́dì, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run níwájú gbogbo wọn, ó bù ú, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í jẹun.