-
Mátíù 15:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Lẹ́yìn náà, èrò rẹpẹtẹ wá bá a, wọ́n mú àwọn èèyàn tó yarọ wá, àwọn aláàbọ̀ ara, afọ́jú, àwọn tí kò lè sọ̀rọ̀ àti ọ̀pọ̀ àwọn míì, wọ́n tẹ́ wọn síbi ẹsẹ̀ rẹ̀, ó sì wò wọ́n sàn.+
-