Mátíù 14:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tó wá sí etíkun, ó rí èrò rẹpẹtẹ, àánú wọn ṣe é,+ ó sì wo àwọn tó ń ṣàìsàn nínú wọn sàn.+ Máàkù 6:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Nígbà tó jáde, ó rí èrò rẹpẹtẹ, àánú wọn sì ṣe é,+ torí wọ́n dà bí àgùntàn tí kò ní olùṣọ́ àgùntàn.+ Ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ wọn ní ọ̀pọ̀ nǹkan.+
34 Nígbà tó jáde, ó rí èrò rẹpẹtẹ, àánú wọn sì ṣe é,+ torí wọ́n dà bí àgùntàn tí kò ní olùṣọ́ àgùntàn.+ Ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ wọn ní ọ̀pọ̀ nǹkan.+