-
Máàkù 8:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Ló bá tún gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú ọkùnrin náà, ọkùnrin náà wá ríran dáadáa. Ojú rẹ̀ tún bẹ̀rẹ̀ sí í ríran, ó sì ń rí gbogbo nǹkan kedere.
-