Sáàmù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọMàá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+ Hébérù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní báyìí, ní òpin àwọn ọjọ́ yìí, ó ti bá wa sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ+ tó yàn ṣe ajogún ohun gbogbo,+ nípasẹ̀ ẹni tó dá àwọn ètò àwọn nǹkan.*+
8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọMàá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+
2 Ní báyìí, ní òpin àwọn ọjọ́ yìí, ó ti bá wa sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ+ tó yàn ṣe ajogún ohun gbogbo,+ nípasẹ̀ ẹni tó dá àwọn ètò àwọn nǹkan.*+