Ìfihàn 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹṣin míì jáde wá, ó jẹ́ aláwọ̀ iná, a sì gba ẹni tó jókòó sórí rẹ̀ láyè láti mú àlàáfíà kúrò ní ayé kí wọ́n lè máa pa ara wọn, a sì fún un ní idà ńlá kan.+
4 Ẹṣin míì jáde wá, ó jẹ́ aláwọ̀ iná, a sì gba ẹni tó jókòó sórí rẹ̀ láyè láti mú àlàáfíà kúrò ní ayé kí wọ́n lè máa pa ara wọn, a sì fún un ní idà ńlá kan.+