Mátíù 24:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ó máa rán àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ jáde pẹ̀lú ìró kàkàkí tó rinlẹ̀, wọ́n sì máa kó àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ jọ látinú atẹ́gùn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, láti ìkángun kan ọ̀run títí dé ìkángun kejì.+
31 Ó máa rán àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ jáde pẹ̀lú ìró kàkàkí tó rinlẹ̀, wọ́n sì máa kó àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ jọ látinú atẹ́gùn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin, láti ìkángun kan ọ̀run títí dé ìkángun kejì.+