Àìsáyà 53:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+ Mátíù 26:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 torí èyí túmọ̀ sí ‘ẹ̀jẹ̀+ májẹ̀mú’ mi,+ tí a máa dà jáde nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn,+ kí wọ́n lè rí ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀.+ Lúùkù 22:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó ṣe bákan náà ní ti ife náà, lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oúnjẹ alẹ́, ó ní: “Ife yìí túmọ̀ sí májẹ̀mú tuntun+ tí a fi ẹ̀jẹ̀ mi dá,*+ tí a máa dà jáde nítorí yín.+
12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+
28 torí èyí túmọ̀ sí ‘ẹ̀jẹ̀+ májẹ̀mú’ mi,+ tí a máa dà jáde nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn,+ kí wọ́n lè rí ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀.+
20 Ó ṣe bákan náà ní ti ife náà, lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oúnjẹ alẹ́, ó ní: “Ife yìí túmọ̀ sí májẹ̀mú tuntun+ tí a fi ẹ̀jẹ̀ mi dá,*+ tí a máa dà jáde nítorí yín.+