-
Mátíù 26:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Pétérù sọ fún un pé: “Àní tó bá tiẹ̀ gba pé kí n kú pẹ̀lú rẹ pàápàá, ó dájú pé mi ò ní sẹ́ ọ.”+ Gbogbo àwọn ọmọ ẹ̀yìn yòókù sọ ohun kan náà.
-