Mátíù 27:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Bí wọ́n ṣe ń jáde lọ, wọ́n rí ọkùnrin ará Kírénè kan tó ń jẹ́ Símónì. Wọ́n fi dandan mú ọkùnrin yìí pé kó gbé òpó igi oró* rẹ̀.+ Lúùkù 23:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Bí wọ́n ṣe ń mú un lọ, wọ́n mú ẹnì kan, ìyẹn Símónì ará Kírénè, ó ń bọ̀ láti ìgbèríko, wọ́n sì gbé òpó igi oró* náà lé e pé kó gbé e tẹ̀ lé Jésù.+
32 Bí wọ́n ṣe ń jáde lọ, wọ́n rí ọkùnrin ará Kírénè kan tó ń jẹ́ Símónì. Wọ́n fi dandan mú ọkùnrin yìí pé kó gbé òpó igi oró* rẹ̀.+
26 Bí wọ́n ṣe ń mú un lọ, wọ́n mú ẹnì kan, ìyẹn Símónì ará Kírénè, ó ń bọ̀ láti ìgbèríko, wọ́n sì gbé òpó igi oró* náà lé e pé kó gbé e tẹ̀ lé Jésù.+