ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 22:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀?+

      Kí nìdí tí o fi jìnnà sí mi láti gbà mí sílẹ̀,

      Tí o sì jìnnà sí igbe ìrora mi?+

  • Mátíù 27:46-49
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Ní nǹkan bíi wákàtí kẹsàn-án, Jésù ké jáde pé: “Élì, Élì, làmá sàbákìtanì?” tó túmọ̀ sí, “Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀?”+ 47 Nígbà tí àwọn kan lára àwọn tó dúró síbẹ̀ gbọ́ èyí, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Ọkùnrin yìí ń pe Èlíjà.”+ 48 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ọ̀kan lára wọn sáré lọ mú kànrìnkàn, ó sì rẹ ẹ́ sínú wáìnì kíkan, ó wá fi sórí ọ̀pá esùsú, ó sì fún un pé kó mu ún.+ 49 Àmọ́ àwọn yòókù sọ pé: “Ẹ fi sílẹ̀! Ká wò ó bóyá Èlíjà máa wá gbà á là.”

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́