Lúùkù 1:57, 58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Nígbà tí ó tó àkókò tí Èlísábẹ́tì máa bímọ, ó bí ọmọkùnrin kan. 58 Àwọn aládùúgbò àti àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ gbọ́ pé Jèhófà* ti ṣàánú rẹ̀ gidigidi, wọ́n sì bá a yọ̀.+
57 Nígbà tí ó tó àkókò tí Èlísábẹ́tì máa bímọ, ó bí ọmọkùnrin kan. 58 Àwọn aládùúgbò àti àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ gbọ́ pé Jèhófà* ti ṣàánú rẹ̀ gidigidi, wọ́n sì bá a yọ̀.+