ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Rúùtù 4:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Kí ọmọ tí Jèhófà yóò fún ọ látọ̀dọ̀ obìnrin yìí+ mú kí ilé rẹ dà bí ilé Pérésì,+ tí Támárì bí fún Júdà.”

  • Rúùtù 4:18, 19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ìlà ìdílé* Pérésì+ nìyí: Pérésì bí Hésírónì;+ 19 Hésírónì bí Rámù; Rámù bí Ámínádábù;+

  • 1 Kíróníkà 2:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Támárì+ ìyàwó ọmọ Júdà bí Pérésì+ àti Síírà fún un. Gbogbo àwọn ọmọ Júdà jẹ́ márùn-ún.

      5 Àwọn ọmọ Pérésì ni Hésírónì àti Hámúlù.+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́