Diutarónómì 8:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, ó rẹ̀ ọ́ sílẹ̀, ó jẹ́ kí ebi pa ọ́,+ ó sì fi mánà bọ́ ọ,+ oúnjẹ tí o kò mọ̀, tí àwọn bàbá rẹ ò sì mọ̀, kí o lè mọ̀ pé kì í ṣe oúnjẹ nìkan ṣoṣo ló ń mú kí èèyàn wà láàyè, àmọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń ti ẹnu Jèhófà jáde ni èèyàn fi ń wà láàyè.+
3 Torí náà, ó rẹ̀ ọ́ sílẹ̀, ó jẹ́ kí ebi pa ọ́,+ ó sì fi mánà bọ́ ọ,+ oúnjẹ tí o kò mọ̀, tí àwọn bàbá rẹ ò sì mọ̀, kí o lè mọ̀ pé kì í ṣe oúnjẹ nìkan ṣoṣo ló ń mú kí èèyàn wà láàyè, àmọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tó ń ti ẹnu Jèhófà jáde ni èèyàn fi ń wà láàyè.+