Àìsáyà 42:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí o lè la àwọn ojú tó fọ́,+Láti mú ẹlẹ́wọ̀n jáde kúrò nínú àjà ilẹ̀Àti àwọn tó jókòó sínú òkùnkùn jáde kúrò ní ẹ̀wọ̀n.+
7 Kí o lè la àwọn ojú tó fọ́,+Láti mú ẹlẹ́wọ̀n jáde kúrò nínú àjà ilẹ̀Àti àwọn tó jókòó sínú òkùnkùn jáde kúrò ní ẹ̀wọ̀n.+