Mátíù 11:25, 26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Nígbà náà, Jésù sọ pé: “Baba, Olúwa ọ̀run àti ayé, mo yìn ọ́ ní gbangba, torí pé o fi àwọn nǹkan yìí pa mọ́ fún àwọn ọlọ́gbọ́n àti àwọn amòye, o sì ti ṣí wọn payá fún àwọn ọmọdé.+ 26 Bẹ́ẹ̀ ni, Baba, torí pé ohun tí o fọwọ́ sí nìyí.
25 Nígbà náà, Jésù sọ pé: “Baba, Olúwa ọ̀run àti ayé, mo yìn ọ́ ní gbangba, torí pé o fi àwọn nǹkan yìí pa mọ́ fún àwọn ọlọ́gbọ́n àti àwọn amòye, o sì ti ṣí wọn payá fún àwọn ọmọdé.+ 26 Bẹ́ẹ̀ ni, Baba, torí pé ohun tí o fọwọ́ sí nìyí.