Jòhánù 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Torí náà, wọ́n se àsè oúnjẹ alẹ́ fún un níbẹ̀, Màtá ń gbé oúnjẹ wá fún wọn,+ Lásárù sì wà lára àwọn tó ń bá a jẹun.*
2 Torí náà, wọ́n se àsè oúnjẹ alẹ́ fún un níbẹ̀, Màtá ń gbé oúnjẹ wá fún wọn,+ Lásárù sì wà lára àwọn tó ń bá a jẹun.*