-
Mátíù 10:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Kódà, gbogbo irun orí yín la ti kà.
-
-
Lúùkù 21:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àmọ́ ìkankan nínú irun orí yín pàápàá kò ní ṣègbé.+
-