Mátíù 6:31, 32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Torí náà, ẹ má ṣàníyàn láé,+ kí ẹ wá sọ pé, ‘Kí la máa jẹ?’ tàbí, ‘Kí la máa mu?’ tàbí, ‘Kí la máa wọ̀?’+ 32 Torí gbogbo nǹkan yìí ni àwọn orílẹ̀-èdè ń wá lójú méjèèjì. Baba yín ọ̀run mọ̀ pé ẹ nílò gbogbo nǹkan yìí.
31 Torí náà, ẹ má ṣàníyàn láé,+ kí ẹ wá sọ pé, ‘Kí la máa jẹ?’ tàbí, ‘Kí la máa mu?’ tàbí, ‘Kí la máa wọ̀?’+ 32 Torí gbogbo nǹkan yìí ni àwọn orílẹ̀-èdè ń wá lójú méjèèjì. Baba yín ọ̀run mọ̀ pé ẹ nílò gbogbo nǹkan yìí.