Jòhánù 12:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Nígbà tí ẹ ṣì ní ìmọ́lẹ̀, ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú ìmọ́lẹ̀ náà, kí ẹ lè di ọmọ ìmọ́lẹ̀.”+ Jésù sọ àwọn nǹkan yìí, ó kúrò níbẹ̀, ó sì lọ fara pa mọ́ fún wọn. Éfésù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 nítorí pé ẹ jẹ́ òkùnkùn nígbà kan rí, àmọ́ ẹ ti di ìmọ́lẹ̀+ báyìí nínú Olúwa.+ Ẹ máa rìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìmọ́lẹ̀, 1 Tẹsalóníkà 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 nítorí gbogbo yín jẹ́ ọmọ ìmọ́lẹ̀ àti ọmọ ọ̀sán.+ Àwa kì í ṣe ti òru tàbí ti òkùnkùn.+
36 Nígbà tí ẹ ṣì ní ìmọ́lẹ̀, ẹ ní ìgbàgbọ́ nínú ìmọ́lẹ̀ náà, kí ẹ lè di ọmọ ìmọ́lẹ̀.”+ Jésù sọ àwọn nǹkan yìí, ó kúrò níbẹ̀, ó sì lọ fara pa mọ́ fún wọn.
8 nítorí pé ẹ jẹ́ òkùnkùn nígbà kan rí, àmọ́ ẹ ti di ìmọ́lẹ̀+ báyìí nínú Olúwa.+ Ẹ máa rìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìmọ́lẹ̀,