-
Mátíù 19:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Jésù bá tẹjú mọ́ wọn, ó sì sọ pé: “Lójú èèyàn, èyí kò ṣeé ṣe, àmọ́ ohun gbogbo ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+
-
-
Máàkù 10:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Jésù wò wọ́n tààrà, ó sì sọ pé: “Lójú èèyàn, kò ṣeé ṣe, àmọ́ kò rí bẹ́ẹ̀ lójú Ọlọ́run, torí ohun gbogbo ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+
-