-
Lúùkù 16:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ẹni tó bá jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun tó kéré jù jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun tó pọ̀ pẹ̀lú, ẹni tó bá sì jẹ́ aláìṣòdodo nínú ohun tó kéré jù jẹ́ aláìṣòdodo nínú ohun tó pọ̀ pẹ̀lú.
-