15 Wọ́n wá dé Jerúsálẹ́mù. Ó wọnú tẹ́ńpìlì níbẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í lé àwọn tó ń tajà àti àwọn tó ń rajà nínú tẹ́ńpìlì síta, ó sì dojú tábìlì àwọn tó ń pààrọ̀ owó dé àti bẹ́ǹṣì àwọn tó ń ta àdàbà,+ 16 kò sì jẹ́ kí ẹnì kankan gbé ohun èlò gba tẹ́ńpìlì kọjá.