-
Máàkù 13:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Tí wọ́n bá sì ń mú yín lọ láti fà yín léni lọ́wọ́, ẹ má ṣàníyàn ṣáájú nípa ohun tí ẹ máa sọ; àmọ́ ohunkóhun tí a bá fún yín ní wákàtí yẹn ni kí ẹ sọ, torí kì í ṣe ẹ̀yin lẹ̀ ń sọ̀rọ̀, ẹ̀mí mímọ́ ni.+
-
-
Ìṣe 6:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ wọn ò lè dúró níwájú rẹ̀ nítorí ọgbọ́n àti ẹ̀mí tó fi ń sọ̀rọ̀.+
-