Mátíù 24:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ ẹni tó bá fara dà á* dé òpin máa rí ìgbàlà.+ Róòmù 5:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ ẹ jẹ́ ká máa yọ̀* nígbà tí a bá wà nínú ìpọ́njú,+ torí a mọ̀ pé ìpọ́njú ń mú ìfaradà wá;+ 4 ìfaradà ní tirẹ̀ ń mú ìtẹ́wọ́gbà wá;+ ìtẹ́wọ́gbà sì ń mú ìrètí wá,+ Hébérù 10:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Nítorí ẹ nílò ìfaradà,+ pé lẹ́yìn tí ẹ ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run, kí ẹ lè rí ohun tí ó ṣèlérí náà gbà. 2 Pétérù 1:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí èyí, ẹ sa gbogbo ipá yín+ láti fi ìwà mímọ́ kún ìgbàgbọ́ yín,+ ìmọ̀ kún ìwà mímọ́ yín,+ 6 ìkóra-ẹni-níjàánu kún ìmọ̀ yín, ìfaradà kún ìkóra-ẹni-níjàánu yín,+ ìfọkànsin Ọlọ́run+ kún ìfaradà yín,
3 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ ẹ jẹ́ ká máa yọ̀* nígbà tí a bá wà nínú ìpọ́njú,+ torí a mọ̀ pé ìpọ́njú ń mú ìfaradà wá;+ 4 ìfaradà ní tirẹ̀ ń mú ìtẹ́wọ́gbà wá;+ ìtẹ́wọ́gbà sì ń mú ìrètí wá,+
5 Nítorí èyí, ẹ sa gbogbo ipá yín+ láti fi ìwà mímọ́ kún ìgbàgbọ́ yín,+ ìmọ̀ kún ìwà mímọ́ yín,+ 6 ìkóra-ẹni-níjàánu kún ìmọ̀ yín, ìfaradà kún ìkóra-ẹni-níjàánu yín,+ ìfọkànsin Ọlọ́run+ kún ìfaradà yín,