Mátíù 26:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jésù sọ fún wọn pé: “Gbogbo yín lẹ máa kọsẹ̀ torí ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí mi lóru òní, torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Màá kọ lu olùṣọ́ àgùntàn, àwọn àgùntàn inú agbo sì máa tú ká.’+ Máàkù 14:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Jésù sì sọ fún wọn pé: “Gbogbo yín lẹ máa kọsẹ̀, torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Màá kọ lu olùṣọ́ àgùntàn,+ àwọn àgùntàn sì máa tú ká.’+ 1 Pétérù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ máa ronú bó ṣe tọ́, ẹ wà lójúfò!+ Èṣù tó jẹ́ ọ̀tá yín ń rìn káàkiri bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù, ó ń wá bó ṣe máa pani jẹ.*+
31 Jésù sọ fún wọn pé: “Gbogbo yín lẹ máa kọsẹ̀ torí ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí mi lóru òní, torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Màá kọ lu olùṣọ́ àgùntàn, àwọn àgùntàn inú agbo sì máa tú ká.’+
27 Jésù sì sọ fún wọn pé: “Gbogbo yín lẹ máa kọsẹ̀, torí a ti kọ ọ́ pé: ‘Màá kọ lu olùṣọ́ àgùntàn,+ àwọn àgùntàn sì máa tú ká.’+
8 Ẹ máa ronú bó ṣe tọ́, ẹ wà lójúfò!+ Èṣù tó jẹ́ ọ̀tá yín ń rìn káàkiri bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù, ó ń wá bó ṣe máa pani jẹ.*+