Lúùkù 18:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ó wá pe àwọn Méjìlá náà sí ẹ̀gbẹ́ kan, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ wò ó! À ń gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù, gbogbo nǹkan tí a tipasẹ̀ àwọn wòlíì kọ sílẹ̀ nípa Ọmọ èèyàn ló sì máa ṣẹ délẹ̀délẹ̀.*+
31 Ó wá pe àwọn Méjìlá náà sí ẹ̀gbẹ́ kan, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ wò ó! À ń gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù, gbogbo nǹkan tí a tipasẹ̀ àwọn wòlíì kọ sílẹ̀ nípa Ọmọ èèyàn ló sì máa ṣẹ délẹ̀délẹ̀.*+