ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 28:5-7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Àmọ́ áńgẹ́lì náà sọ fún àwọn obìnrin náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù, torí mo mọ̀ pé Jésù tí wọ́n kàn mọ́gi lẹ̀ ń wá.+ 6 Kò sí níbí, torí a ti jí i dìde, bó ṣe sọ gẹ́lẹ́.+ Ẹ wá wo ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí. 7 Kí ẹ tètè lọ sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé a ti jí i dìde, torí ẹ wò ó! ó ń lọ sí Gálílì ṣáájú yín.+ Ẹ máa rí i níbẹ̀. Ẹ wò ó! Mo ti sọ fún yín.”+

  • Máàkù 16:5-7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nígbà tí wọ́n wọnú ibojì náà, wọ́n rí ọ̀dọ́kùnrin kan tó jókòó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀tún, ó wọ aṣọ funfun, ẹnu sì yà wọ́n. 6 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ má ṣe jẹ́ kó yà yín lẹ́nu.+ Jésù ará Násárẹ́tì tí wọ́n kàn mọ́gi lẹ̀ ń wá. A ti jí i dìde.+ Kò sí níbí. Ẹ wò ó, ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí nìyí.+ 7 Àmọ́ ẹ lọ, ẹ sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àti Pétérù pé, ‘Ó ń lọ sí Gálílì ṣáájú yín.+ Ẹ máa rí i níbẹ̀, bó ṣe sọ fún yín.’”+

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́